Mátíù 26:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nígbà tó di ìrọ̀lẹ́,+ òun àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn méjìlá (12) jókòó* sídìí tábìlì.+ Lúùkù 22:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tí wákàtí náà wá tó, ó jókòó* sídìí tábìlì pẹ̀lú àwọn àpọ́sítélì.+