11 Tí ẹnikẹ́ni bá ń sọ̀rọ̀, kó sọ ọ́ bíi pé ó ń kéde ọ̀rọ̀ Ọlọ́run; tí ẹnikẹ́ni bá ń ṣe ìránṣẹ́, kó ṣe é bí ẹni tó gbára lé okun tí Ọlọ́run ń fúnni;+ ká lè yin Ọlọ́run lógo nínú ohun gbogbo+ nípasẹ̀ Jésù Kristi. Ògo àti agbára jẹ́ tirẹ̀ títí láé àti láéláé. Àmín.