Éfésù 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni gbogbo ara+ ti para pọ̀ di ọ̀kan, tí a sì mú kí wọ́n fọwọ́ sowọ́ pọ̀ nípasẹ̀ gbogbo oríkèé tó ń pèsè ohun tí a nílò. Tí ẹ̀yà ara kọ̀ọ̀kan bá ń ṣiṣẹ́ bó ṣe yẹ, èyí á mú kí ara máa dàgbà sí i bó ṣe ń gbé ara rẹ̀ ró nínú ìfẹ́.+
16 Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni gbogbo ara+ ti para pọ̀ di ọ̀kan, tí a sì mú kí wọ́n fọwọ́ sowọ́ pọ̀ nípasẹ̀ gbogbo oríkèé tó ń pèsè ohun tí a nílò. Tí ẹ̀yà ara kọ̀ọ̀kan bá ń ṣiṣẹ́ bó ṣe yẹ, èyí á mú kí ara máa dàgbà sí i bó ṣe ń gbé ara rẹ̀ ró nínú ìfẹ́.+