Róòmù 8:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ṣùgbọ́n tí a bá ń retí+ ohun tí a kò rí,+ a ó máa fi ìfaradà dúró dè é+ lójú méjèèjì. Róòmù 12:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ jẹ́ kí ìrètí tí ẹ ní máa fún yín láyọ̀. Ẹ máa fara da ìpọ́njú.+ Ẹ máa tẹra mọ́ àdúrà gbígbà.+