1 Kọ́ríńtì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí Kristi ò rán mi pé kí n lọ máa batisí, iṣẹ́ kíkéde ìhìn rere ló rán mi;+ kì í sì í ṣe pẹ̀lú ọgbọ́n ọ̀rọ̀ sísọ,* kí a má bàa sọ igi oró* Kristi di ohun tí kò wúlò.
17 Nítorí Kristi ò rán mi pé kí n lọ máa batisí, iṣẹ́ kíkéde ìhìn rere ló rán mi;+ kì í sì í ṣe pẹ̀lú ọgbọ́n ọ̀rọ̀ sísọ,* kí a má bàa sọ igi oró* Kristi di ohun tí kò wúlò.