1 Tímótì 2:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí obìnrin kẹ́kọ̀ọ́ ní ìdákẹ́jẹ́ẹ́* kó sì máa tẹrí ba délẹ̀délẹ̀.+ 12 Mi ò fọwọ́ sí kí obìnrin kọ́ni tàbí kó pàṣẹ lé ọkùnrin lórí, àmọ́ kí ó dákẹ́.*+
11 Kí obìnrin kẹ́kọ̀ọ́ ní ìdákẹ́jẹ́ẹ́* kó sì máa tẹrí ba délẹ̀délẹ̀.+ 12 Mi ò fọwọ́ sí kí obìnrin kọ́ni tàbí kó pàṣẹ lé ọkùnrin lórí, àmọ́ kí ó dákẹ́.*+