Gálátíà 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ní tèmi, mi ò ní yangàn láé, àfi nípa òpó igi oró* Olúwa wa Jésù Kristi,+ ẹni tí a tipasẹ̀ rẹ̀ sọ ayé di òkú* lójú tèmi àti èmi lójú ti ayé.
14 Ní tèmi, mi ò ní yangàn láé, àfi nípa òpó igi oró* Olúwa wa Jésù Kristi,+ ẹni tí a tipasẹ̀ rẹ̀ sọ ayé di òkú* lójú tèmi àti èmi lójú ti ayé.