1 Kọ́ríńtì 14:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Tí ẹnì kan bá ń fi èdè fọ̀,* kí ó fi mọ sí méjì tàbí ó pọ̀ jù, mẹ́ta, kí wọ́n máa sọ̀rọ̀ ní ọ̀kan tẹ̀ lé òmíràn, kí ẹnì kan sì máa ṣe ìtúmọ̀.*+
27 Tí ẹnì kan bá ń fi èdè fọ̀,* kí ó fi mọ sí méjì tàbí ó pọ̀ jù, mẹ́ta, kí wọ́n máa sọ̀rọ̀ ní ọ̀kan tẹ̀ lé òmíràn, kí ẹnì kan sì máa ṣe ìtúmọ̀.*+