-
Ìṣe 18:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Lẹ́yìn èyí, ó kúrò ní Áténì, ó sì wá sí Kọ́ríńtì.
-
-
Ìṣe 18:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Torí náà, ó lo ọdún kan àti oṣù mẹ́fà níbẹ̀, ó ń kọ́ni ní ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láàárín wọn.
-