Ìṣe 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́, ó fọwọ́ sọ fún wọn pé kí wọ́n dákẹ́, ó sì sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ bí Jèhófà* ṣe mú un jáde kúrò nínú ẹ̀wọ̀n, ó sọ pé: “Ẹ sọ àwọn nǹkan yìí fún Jémíìsì+ àti àwọn ará.” Lẹ́yìn náà, ó jáde, ó sì rin ìrìn àjò lọ sí ibòmíì.
17 Àmọ́, ó fọwọ́ sọ fún wọn pé kí wọ́n dákẹ́, ó sì sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ bí Jèhófà* ṣe mú un jáde kúrò nínú ẹ̀wọ̀n, ó sọ pé: “Ẹ sọ àwọn nǹkan yìí fún Jémíìsì+ àti àwọn ará.” Lẹ́yìn náà, ó jáde, ó sì rin ìrìn àjò lọ sí ibòmíì.