Fílípì 3:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́, ìlú ìbílẹ̀ wa*+ wà ní ọ̀run,+ a sì ń dúró de olùgbàlà láti ibẹ̀ lójú méjèèjì, ìyẹn Jésù Kristi Olúwa,+ 21 ẹni tó máa fi agbára ńlá rẹ̀ yí ara rírẹlẹ̀ wa pa dà kí ó lè dà bí* ara ológo tirẹ̀,+ èyí tó mú kó lè fi ohun gbogbo sábẹ́ ara rẹ̀.+
20 Àmọ́, ìlú ìbílẹ̀ wa*+ wà ní ọ̀run,+ a sì ń dúró de olùgbàlà láti ibẹ̀ lójú méjèèjì, ìyẹn Jésù Kristi Olúwa,+ 21 ẹni tó máa fi agbára ńlá rẹ̀ yí ara rírẹlẹ̀ wa pa dà kí ó lè dà bí* ara ológo tirẹ̀,+ èyí tó mú kó lè fi ohun gbogbo sábẹ́ ara rẹ̀.+