2 Kọ́ríńtì 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kódà, àwa tí a wà nínú àgọ́ yìí ń kérora, ìdààmú bò wá mọ́lẹ̀, torí pé a ò fẹ́ bọ́ èyí kúrò, àmọ́ a fẹ́ gbé èkejì wọ̀,+ kí ìyè lè gbé èyí tó lè kú mì.+
4 Kódà, àwa tí a wà nínú àgọ́ yìí ń kérora, ìdààmú bò wá mọ́lẹ̀, torí pé a ò fẹ́ bọ́ èyí kúrò, àmọ́ a fẹ́ gbé èkejì wọ̀,+ kí ìyè lè gbé èyí tó lè kú mì.+