Fílípì 2:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ní báyìí, mo ní ìrètí pé, tí Jésù Olúwa bá fẹ́, màá rán Tímótì+ sí yín láìpẹ́, kí ara mi lè yá gágá nígbà tí mo bá gbọ́ ìròyìn nípa yín. 20 Nítorí mi ò ní ẹlòmíì tó níwà bíi tirẹ̀ tó máa fi òótọ́ inú bójú tó ọ̀rọ̀ yín.
19 Ní báyìí, mo ní ìrètí pé, tí Jésù Olúwa bá fẹ́, màá rán Tímótì+ sí yín láìpẹ́, kí ara mi lè yá gágá nígbà tí mo bá gbọ́ ìròyìn nípa yín. 20 Nítorí mi ò ní ẹlòmíì tó níwà bíi tirẹ̀ tó máa fi òótọ́ inú bójú tó ọ̀rọ̀ yín.