Róòmù 8:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 torí pé ríronú nípa àwọn nǹkan tara ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run,+ nítorí kò sí lábẹ́ òfin Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni, kò lè sí níbẹ̀. 8 Torí náà, àwọn tó ń gbé ìgbé ayé tara kò lè ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.
7 torí pé ríronú nípa àwọn nǹkan tara ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run,+ nítorí kò sí lábẹ́ òfin Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni, kò lè sí níbẹ̀. 8 Torí náà, àwọn tó ń gbé ìgbé ayé tara kò lè ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run.