Róòmù 9:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, kò sí lọ́wọ́ ẹni tó ń fẹ́ tàbí lọ́wọ́ ìsapá* ẹni náà, àmọ́ ọwọ́ Ọlọ́run tó ń ṣàánú ló wà.+
16 Nítorí náà, kò sí lọ́wọ́ ẹni tó ń fẹ́ tàbí lọ́wọ́ ìsapá* ẹni náà, àmọ́ ọwọ́ Ọlọ́run tó ń ṣàánú ló wà.+