1 Kọ́ríńtì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ohun tí mo ní lọ́kàn ni pé, kálukú yín ń sọ pé: “Èmi jẹ́ ti Pọ́ọ̀lù,” “Èmi jẹ́ ti Àpólò,”+ “Èmi jẹ́ ti Kéfà,”* “Èmi jẹ́ ti Kristi.”
12 Ohun tí mo ní lọ́kàn ni pé, kálukú yín ń sọ pé: “Èmi jẹ́ ti Pọ́ọ̀lù,” “Èmi jẹ́ ti Àpólò,”+ “Èmi jẹ́ ti Kéfà,”* “Èmi jẹ́ ti Kristi.”