-
Jòhánù 17:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Mo gbàdúrà nípa wọn; kì í ṣe nípa ayé, àmọ́ nípa àwọn tí o fún mi, torí pé ìwọ lo ni wọ́n;
-
-
2 Kọ́ríńtì 10:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ẹ̀ ń wo àwọn nǹkan bí wọ́n ṣe rí lójú. Bí ẹnikẹ́ni bá dá ara rẹ̀ lójú pé òun jẹ́ ti Kristi, kí ó rántí òtítọ́ yìí pé: Bí òun ṣe jẹ́ ti Kristi, bẹ́ẹ̀ ni àwa náà ṣe jẹ́ ti Kristi.
-