ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 12:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Torí nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a fún mi, mo sọ fún gbogbo ẹni tó wà láàárín yín níbẹ̀ pé kó má ro ara rẹ̀ ju bó ṣe yẹ lọ,+ àmọ́ kó máa ronú lọ́nà tó fi hàn pé ó láròjinlẹ̀, bí Ọlọ́run ṣe fún kálukú ní ìwọ̀n ìgbàgbọ́.*+

  • 2 Kọ́ríńtì 12:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ẹ̀rù ń bà mí pé tí mo bá dé, mo lè má bá yín bí mo ṣe fẹ́, mo sì lè má rí bí ẹ ṣe rò, dípò bẹ́ẹ̀, ó lè jẹ́ wàhálà, owú, ìbínú ńlá, awuyewuye, sísọ̀rọ̀ ẹni láìdáa, ọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́,* ìgbéraga àti rúdurùdu ni màá bá nílẹ̀.

  • 3 Jòhánù 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Mo kọ̀wé kan sí ìjọ, àmọ́ Díótíréfè tó fẹ́ fi ara rẹ̀ ṣe olórí láàárín wọn,+ kì í fi ìrẹ̀lẹ̀ gba ohunkóhun tí a bá sọ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́