Róòmù 16:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo rọ̀ yín pé kí ẹ máa ṣọ́ àwọn tó ń fa ìyapa àti ìkọ̀sẹ̀ tó lòdì sí ẹ̀kọ́ tí ẹ ti kọ́, kí ẹ sì yẹra fún wọn.+
17 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo rọ̀ yín pé kí ẹ máa ṣọ́ àwọn tó ń fa ìyapa àti ìkọ̀sẹ̀ tó lòdì sí ẹ̀kọ́ tí ẹ ti kọ́, kí ẹ sì yẹra fún wọn.+