1 Tẹsalóníkà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Òótọ́ ibẹ̀ ni pé, kì í ṣe pé ọ̀rọ̀ Jèhófà* ti dún jáde látọ̀dọ̀ yín ní Makedóníà àti Ákáyà nìkan ni, àmọ́ ìgbàgbọ́ yín nínú Ọlọ́run ti tàn káàkiri níbi gbogbo,+ débi pé a kò nílò láti sọ ohunkóhun.
8 Òótọ́ ibẹ̀ ni pé, kì í ṣe pé ọ̀rọ̀ Jèhófà* ti dún jáde látọ̀dọ̀ yín ní Makedóníà àti Ákáyà nìkan ni, àmọ́ ìgbàgbọ́ yín nínú Ọlọ́run ti tàn káàkiri níbi gbogbo,+ débi pé a kò nílò láti sọ ohunkóhun.