15 Torí àlùfáà àgbà tí a ní kì í ṣe ẹni tí kò lè bá wa kẹ́dùn fún àwọn àìlera wa,+ àmọ́ ó jẹ́ ẹni tí a ti dán wò ní gbogbo ọ̀nà bíi tiwa, àmọ́ tí kò ní ẹ̀ṣẹ̀.+
26 Torí irú àlùfáà àgbà yìí ló yẹ wá, ẹni tó jẹ́ adúróṣinṣin, aláìṣẹ̀, aláìlẹ́gbin,+ ẹni tí a yà sọ́tọ̀ láàárín àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, tí a sì gbé ga ju ọ̀run lọ.+