Fílípì 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo ní okun láti ṣe ohun gbogbo nípasẹ̀ ẹni tó ń fún mi lágbára.+ Ìfihàn 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 ‘Mo mọ ìpọ́njú àti ipò òṣì rẹ—àmọ́ ọlọ́rọ̀ ni ọ́+—àti ọ̀rọ̀ òdì àwọn tó ń pe ara wọn ní Júù, síbẹ̀ tí wọn kì í ṣe Júù, àmọ́ sínágọ́gù Sátánì ni wọ́n.+
9 ‘Mo mọ ìpọ́njú àti ipò òṣì rẹ—àmọ́ ọlọ́rọ̀ ni ọ́+—àti ọ̀rọ̀ òdì àwọn tó ń pe ara wọn ní Júù, síbẹ̀ tí wọn kì í ṣe Júù, àmọ́ sínágọ́gù Sátánì ni wọ́n.+