Fílípì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 torí mo mọ̀ pé èyí máa yọrí sí ìgbàlà mi nípasẹ̀ ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ yín+ àti ìtìlẹyìn ẹ̀mí Jésù Kristi.+ Fílémónì 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Bákan náà, mo tún fẹ́ kí o bá mi ṣètò ibi tí màá dé sí, torí mo ní ìrètí pé wọ́n á jẹ́ kí n pa dà sọ́dọ̀ yín,* lọ́lá àdúrà tí ẹ̀ ń gbà fún mi.+
19 torí mo mọ̀ pé èyí máa yọrí sí ìgbàlà mi nípasẹ̀ ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ yín+ àti ìtìlẹyìn ẹ̀mí Jésù Kristi.+
22 Bákan náà, mo tún fẹ́ kí o bá mi ṣètò ibi tí màá dé sí, torí mo ní ìrètí pé wọ́n á jẹ́ kí n pa dà sọ́dọ̀ yín,* lọ́lá àdúrà tí ẹ̀ ń gbà fún mi.+