Léfítíkù 26:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Màá gbé àgọ́ ìjọsìn mi sáàárín yín,+ mi* ò sì ní kọ̀ yín. 12 Èmi yóò máa rìn láàárín yín, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run yín,+ ẹ̀yin ní tiyín, yóò sì jẹ́ èèyàn mi.+ Ìsíkíẹ́lì 37:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àgọ́* mi yóò wà pẹ̀lú* wọn, èmi yóò di Ọlọ́run wọn, wọn yóò sì di èèyàn mi.+
11 Màá gbé àgọ́ ìjọsìn mi sáàárín yín,+ mi* ò sì ní kọ̀ yín. 12 Èmi yóò máa rìn láàárín yín, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run yín,+ ẹ̀yin ní tiyín, yóò sì jẹ́ èèyàn mi.+