Róòmù 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nínú ìfẹ́ ará, ẹ ní ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ fún ara yín. Nínú bíbu ọlá fún ara yín, ẹ mú ipò iwájú.*+ 2 Kọ́ríńtì 6:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìfẹ́ tí a ní sí yín kò ní ààlà,*+ àmọ́ ẹ ti pààlà sí ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ tí ẹ ní sí wa. 13 Torí náà, mò ń bá yín sọ̀rọ̀ bí ẹni ń bá àwọn ọmọ mi sọ̀rọ̀, ẹ̀yin náà, ẹ ṣí ọkàn yín sílẹ̀ pátápátá.*+
12 Ìfẹ́ tí a ní sí yín kò ní ààlà,*+ àmọ́ ẹ ti pààlà sí ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ tí ẹ ní sí wa. 13 Torí náà, mò ń bá yín sọ̀rọ̀ bí ẹni ń bá àwọn ọmọ mi sọ̀rọ̀, ẹ̀yin náà, ẹ ṣí ọkàn yín sílẹ̀ pátápátá.*+