Fílípì 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́, bí a tilẹ̀ ń tú mi jáde bí ọrẹ ohun mímu+ sórí ẹbọ+ àti iṣẹ́ mímọ́* tí ìgbàgbọ́ yín ń mú kí ẹ ṣe, inú mi ń dùn, mo sì bá gbogbo yín yọ̀. Fílémónì 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Arákùnrin mi, nígbà tí mo gbọ́ nípa ìfẹ́ rẹ, inú mi dùn gan-an, ara sì tù mí torí pé o ti mú kí ara tu àwọn ẹni mímọ́.*
17 Àmọ́, bí a tilẹ̀ ń tú mi jáde bí ọrẹ ohun mímu+ sórí ẹbọ+ àti iṣẹ́ mímọ́* tí ìgbàgbọ́ yín ń mú kí ẹ ṣe, inú mi ń dùn, mo sì bá gbogbo yín yọ̀.
7 Arákùnrin mi, nígbà tí mo gbọ́ nípa ìfẹ́ rẹ, inú mi dùn gan-an, ara sì tù mí torí pé o ti mú kí ara tu àwọn ẹni mímọ́.*