-
2 Kọ́ríńtì 12:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Mo rọ Títù pé kó wá sọ́dọ̀ yín, mo sì rán arákùnrin kan pẹ̀lú rẹ̀. Títù ò yàn yín jẹ rárá, àbí ó ṣe bẹ́ẹ̀?+ Irú ẹ̀mí kan náà la ní, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́? Ipa ọ̀nà kan náà la sì ń rìn, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́?
-