-
1 Kọ́ríńtì 16:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ṣùgbọ́n màá wá sọ́dọ̀ yín tí mo bá ti kọjá ní Makedóníà, torí mo máa gba Makedóníà kọjá;+ 6 ó sì ṣeé ṣe kí n dúró tàbí kí n tiẹ̀ lo ìgbà òtútù pẹ̀lú yín, kí ẹ lè sìn mí dé ọ̀nà ibi tí mo bá ń lọ.
-