Sáàmù 112:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ti pín nǹkan fún àwọn èèyàn káàkiri;* ó ti fún àwọn aláìní.+ צ [Sádì] Òdodo rẹ̀ wà títí láé.+ ק [Kófì] A ó gbé agbára* rẹ̀ ga nínú ògo.
9 Ó ti pín nǹkan fún àwọn èèyàn káàkiri;* ó ti fún àwọn aláìní.+ צ [Sádì] Òdodo rẹ̀ wà títí láé.+ ק [Kófì] A ó gbé agbára* rẹ̀ ga nínú ògo.