-
Òwe 26:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ṣe o ti rí ẹni tó rò pé òun gbọ́n?+
Ìrètí wà fún òmùgọ̀ jù ú lọ.
-
-
Gálátíà 6:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Tí ẹnì kan bá rò pé òun jẹ́ nǹkan kan nígbà tí kò jẹ́ nǹkan kan,+ ó ń tan ara rẹ̀ jẹ ni.
-