Róòmù 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nítorí mo sọ fún yín pé Kristi di òjíṣẹ́ àwọn tó dádọ̀dọ́*+ nítorí pé Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́, kí ó lè fìdí ìlérí tí Ó ṣe fún àwọn baba ńlá+ wọn múlẹ̀,
8 Nítorí mo sọ fún yín pé Kristi di òjíṣẹ́ àwọn tó dádọ̀dọ́*+ nítorí pé Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́, kí ó lè fìdí ìlérí tí Ó ṣe fún àwọn baba ńlá+ wọn múlẹ̀,