-
Gálátíà 2:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 nítorí ẹni tó fún Pétérù lágbára láti ṣe iṣẹ́ àpọ́sítélì láàárín àwọn tó dádọ̀dọ́, fún èmi náà lágbára láti ṣe é láàárín àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè,+
-