2 Kọ́ríńtì 11:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ṣé òjíṣẹ́ Kristi ni wọ́n? Mo fèsì bí ayírí, mo jẹ́ òjíṣẹ́ Kristi lọ́nà tó ta wọ́n yọ: mo ti ṣiṣẹ́ jù wọ́n lọ,+ wọ́n ti jù mí sẹ́wọ̀n lọ́pọ̀ ìgbà,+ wọ́n ti lù mí láìmọye ìgbà, ọ̀pọ̀ ìgbà sì ni ẹ̀mí mi ti fẹ́rẹ̀ẹ́ bọ́.+
23 Ṣé òjíṣẹ́ Kristi ni wọ́n? Mo fèsì bí ayírí, mo jẹ́ òjíṣẹ́ Kristi lọ́nà tó ta wọ́n yọ: mo ti ṣiṣẹ́ jù wọ́n lọ,+ wọ́n ti jù mí sẹ́wọ̀n lọ́pọ̀ ìgbà,+ wọ́n ti lù mí láìmọye ìgbà, ọ̀pọ̀ ìgbà sì ni ẹ̀mí mi ti fẹ́rẹ̀ẹ́ bọ́.+