-
Fílípì 4:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Mo yọ̀ gidigidi nínú Olúwa pé ní báyìí ẹ ti jẹ́ kí ọ̀rọ̀ mi pa dà máa jẹ yín lọ́kàn.+ Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọ̀rọ̀ mi ń jẹ yín lọ́kàn tẹ́lẹ̀, ẹ ò rí àyè láti fi hàn bẹ́ẹ̀.
-