1 Jòhánù 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹni mímọ́ ti yàn yín,+ gbogbo yín sì ní ìmọ̀. 1 Jòhánù 2:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní tiyín, yíyàn tó yàn yín+ kò kúrò nínú yín, ẹ ò sì nílò kí ẹnikẹ́ni máa kọ́ yín; àmọ́, yíyàn tó yàn yín ń kọ́ yín ní ohun gbogbo,+ òótọ́ ni, kì í ṣe irọ́. Kí ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀ bó ṣe kọ́ yín gẹ́lẹ́.+
27 Ní tiyín, yíyàn tó yàn yín+ kò kúrò nínú yín, ẹ ò sì nílò kí ẹnikẹ́ni máa kọ́ yín; àmọ́, yíyàn tó yàn yín ń kọ́ yín ní ohun gbogbo,+ òótọ́ ni, kì í ṣe irọ́. Kí ẹ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀ bó ṣe kọ́ yín gẹ́lẹ́.+