2 Kọ́ríńtì 6:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 àmọ́ ní gbogbo ọ̀nà, à ń dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run,+ nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú ìṣòro,+ 5 nínú lílù, nínú ẹ̀wọ̀n,+ nínú rúkèrúdò, nínú iṣẹ́ àṣekára, nínú àìsùn, nínú àìrí oúnjẹ jẹ;+
4 àmọ́ ní gbogbo ọ̀nà, à ń dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run,+ nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú ìṣòro,+ 5 nínú lílù, nínú ẹ̀wọ̀n,+ nínú rúkèrúdò, nínú iṣẹ́ àṣekára, nínú àìsùn, nínú àìrí oúnjẹ jẹ;+