Ìṣe 22:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Àmọ́ nígbà tí mo pa dà sí Jerúsálẹ́mù,+ tí mo sì ń gbàdúrà nínú tẹ́ńpìlì, mo bọ́ sójú ìran, 18 mo sì rí i tí ó sọ fún mi pé: ‘Ṣe kíá, kí o sì tètè jáde kúrò ní Jerúsálẹ́mù, torí pé wọn ò ní gba ẹ̀rí tí o máa jẹ́ nípa mi.’+
17 “Àmọ́ nígbà tí mo pa dà sí Jerúsálẹ́mù,+ tí mo sì ń gbàdúrà nínú tẹ́ńpìlì, mo bọ́ sójú ìran, 18 mo sì rí i tí ó sọ fún mi pé: ‘Ṣe kíá, kí o sì tètè jáde kúrò ní Jerúsálẹ́mù, torí pé wọn ò ní gba ẹ̀rí tí o máa jẹ́ nípa mi.’+