ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 14:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nítorí náà, wọ́n lo ọ̀pọ̀ àkókò láti fi ìgboyà sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ àṣẹ Jèhófà,* ẹni tí ó jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀ bí ó ṣe jẹ́ kí wọ́n ṣe àwọn iṣẹ́ àmì àti àwọn iṣẹ́ ìyanu.*+

  • Ìṣe 15:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ni gbogbo wọn bá dákẹ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í fetí sílẹ̀ bí Bánábà àti Pọ́ọ̀lù ṣe ń ròyìn ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* tí Ọlọ́run ti ṣe nípasẹ̀ wọn láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.

  • Róòmù 15:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Torí pé mi ò ní sọ nǹkan míì àfi àwọn ohun tí Kristi ti ṣe nípasẹ̀ mi kí àwọn orílẹ̀-èdè lè wá di onígbọràn, nípa ọ̀rọ̀ àti ìṣe mi, 19 pẹ̀lú agbára àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu,*+ pẹ̀lú agbára ẹ̀mí Ọlọ́run, tó fi jẹ́ pé láti Jerúsálẹ́mù títí mo fi lọ yí ká dé Ílíríkónì ni mo ti wàásù ìhìn rere nípa Kristi+ kúnnákúnná.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́