-
1 Kọ́ríńtì 4:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Kì í ṣe kí n lè dójú tì yín ni mo ṣe ń kọ àwọn nǹkan yìí sí yín, àmọ́ kí n lè gbà yín níyànjú bí àwọn ọmọ mi tó jẹ́ àyànfẹ́.
-