Lúùkù 15:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Kí ẹ tún mú ọmọ màlúù tó sanra wá, kí ẹ dúńbú rẹ̀, ká jọ jẹun, ká sì yọ̀, 24 torí pé ọmọ mi yìí kú, àmọ́ ó ti pa dà wà láàyè;+ ó sọ nù, a sì rí i.’ Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í gbádùn ara wọn.
23 Kí ẹ tún mú ọmọ màlúù tó sanra wá, kí ẹ dúńbú rẹ̀, ká jọ jẹun, ká sì yọ̀, 24 torí pé ọmọ mi yìí kú, àmọ́ ó ti pa dà wà láàyè;+ ó sọ nù, a sì rí i.’ Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í gbádùn ara wọn.