-
2 Kọ́ríńtì 4:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Tí ìhìn rere tí à ń kéde bá wà lábẹ́ ìbòjú lóòótọ́, á jẹ́ pé ó wà lábẹ́ ìbòjú láàárín àwọn tó ń ṣègbé,