-
Ẹ́kísódù 34:33-35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Tí Mósè bá ti bá wọn sọ̀rọ̀ tán, á fi nǹkan bojú.+ 34 Àmọ́ tí Mósè bá fẹ́ wọlé lọ bá Jèhófà sọ̀rọ̀, á ṣí ìbòjú náà kúrò títí á fi jáde.+ Ó wá jáde, ó sì sọ àwọn àṣẹ tó gbà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ 35 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì rí i pé ìtànṣán ń jáde lára awọ ojú Mósè; torí náà, Mósè lo ìbòjú náà títí ó fi wọlé lọ bá Ọlọ́run* sọ̀rọ̀.+
-