6 Torí Ọlọ́run ni ẹni tó sọ pé: “Kí ìmọ́lẹ̀ tàn láti inú òkùnkùn,”+ ó sì ti tan ìmọ́lẹ̀ sí ọkàn wa+ láti mú kí ìmọ̀ ológo nípa Ọlọ́run mọ́lẹ̀ nípasẹ̀ ojú Kristi.
23 Torí náà, ẹ máa di tuntun nínú agbára tó ń darí ìrònú yín,*+24 kí ẹ sì gbé ìwà tuntun wọ̀,+ èyí tí a dá gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run nínú òdodo tòótọ́ àti ìdúróṣinṣin.