2 Kọ́ríńtì 6:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 A ò ṣe ohun tó lè fa ìkọ̀sẹ̀ lọ́nàkọnà, kí iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa má bàa ní àbùkù;+ 4 àmọ́ ní gbogbo ọ̀nà, à ń dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run,+ nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú ìṣòro,+
3 A ò ṣe ohun tó lè fa ìkọ̀sẹ̀ lọ́nàkọnà, kí iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa má bàa ní àbùkù;+ 4 àmọ́ ní gbogbo ọ̀nà, à ń dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run,+ nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú ìṣòro,+