Àìsáyà 64:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ ní báyìí, Jèhófà, ìwọ ni Bàbá wa.+ Àwa ni amọ̀, ìwọ sì ni Ẹni tó mọ wá;*+Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa. Ìṣe 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ Olúwa sọ fún un pé: “Lọ! nítorí ohun èlò tí a ti yàn ni ọkùnrin yìí jẹ́ fún mi+ láti mú orúkọ mi lọ sọ́dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè+ àti àwọn ọba+ àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. 1 Kọ́ríńtì 15:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Ọkùnrin àkọ́kọ́ wá láti ayé, erùpẹ̀ sì ni a fi dá a;+ ọkùnrin kejì wá láti ọ̀run.+
8 Àmọ́ ní báyìí, Jèhófà, ìwọ ni Bàbá wa.+ Àwa ni amọ̀, ìwọ sì ni Ẹni tó mọ wá;*+Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni gbogbo wa.
15 Àmọ́ Olúwa sọ fún un pé: “Lọ! nítorí ohun èlò tí a ti yàn ni ọkùnrin yìí jẹ́ fún mi+ láti mú orúkọ mi lọ sọ́dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè+ àti àwọn ọba+ àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.