Róòmù 8:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nítorí mo gbà pé àwọn ìyà àsìkò yìí kò já mọ́ nǹkan kan tí a bá fi wé ògo tí a máa fi hàn nínú wa.+ 2 Tímótì 2:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé: Ó dájú pé tí a bá jọ kú, a tún jọ máa wà láàyè;+ 12 tí a bá ń fara dà á nìṣó, a tún jọ máa jọba;+ tí a bá sẹ́ ẹ, òun náà máa sẹ́ wa;+
18 Nítorí mo gbà pé àwọn ìyà àsìkò yìí kò já mọ́ nǹkan kan tí a bá fi wé ògo tí a máa fi hàn nínú wa.+
11 Ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé: Ó dájú pé tí a bá jọ kú, a tún jọ máa wà láàyè;+ 12 tí a bá ń fara dà á nìṣó, a tún jọ máa jọba;+ tí a bá sẹ́ ẹ, òun náà máa sẹ́ wa;+