Ìṣe 22:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó sọ pé: ‘Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa ti yàn ọ́ láti wá mọ ìfẹ́ rẹ̀, láti rí olódodo náà+ àti láti gbọ́ ohùn ẹnu rẹ̀, 15 torí o máa jẹ́ ẹlẹ́rìí rẹ̀ láti sọ ohun tí o ti rí, tí o sì ti gbọ́+ fún gbogbo èèyàn.
14 Ó sọ pé: ‘Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa ti yàn ọ́ láti wá mọ ìfẹ́ rẹ̀, láti rí olódodo náà+ àti láti gbọ́ ohùn ẹnu rẹ̀, 15 torí o máa jẹ́ ẹlẹ́rìí rẹ̀ láti sọ ohun tí o ti rí, tí o sì ti gbọ́+ fún gbogbo èèyàn.