-
1 Kọ́ríńtì 15:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ nípa inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run, mo jẹ́ ohun tí mo jẹ́. Inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀ lórí mi kò já sí asán, àmọ́ mo ṣiṣẹ́ ju gbogbo wọn lọ; síbẹ̀ kì í ṣe èmi, inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run tó wà pẹ̀lú mi ni.
-