-
Jẹ́nẹ́sísì 16:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Sáráì ìyàwó Ábúrámù kò bí ọmọ kankan+ fún un, àmọ́ ó ní ìránṣẹ́ kan tó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Íjíbítì, Hágárì+ ni orúkọ rẹ̀. 2 Sáráì wá sọ fún Ábúrámù pé: “Jọ̀ọ́, gbọ́ ohun tí mo fẹ́ sọ! Jèhófà ò jẹ́ kí n bímọ. Jọ̀ọ́, bá ìránṣẹ́ mi ní àṣepọ̀. Bóyá mo lè ní ọmọ nípasẹ̀ rẹ̀.”+ Ábúrámù sì fetí sí ohun tí Sáráì sọ.
-