-
Ẹ́kísódù 19:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Jèhófà wá sọ̀ kalẹ̀ sórí Òkè Sínáì. Lẹ́yìn náà, Jèhófà pe Mósè wá sí orí òkè náà, Mósè sì gòkè lọ.+
-
-
Ẹ́kísódù 24:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wá bá mi lórí òkè, kí o sì dúró síbẹ̀. Màá fún ọ ní àwọn wàláà òkúta tí èmi yóò kọ òfin àti àṣẹ sí láti fún àwọn èèyàn náà ní ìtọ́ni.”+
-